Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 28:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rú ẹbọ sí òrìṣà àwọn Dámásíkù, ẹni tí ó sẹ́gun wọn, nítorí ó rò wí pé, “Nítorí àwọn òrìṣà àwọn síríà ti ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọn kí ó bà lè ràn mí lọ́wọ́.” Ṣùgbọ́n àwọn ni ìparun rẹ̀ àti ti gbogbo Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:23 ni o tọ