Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 28:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsinyìí ẹ gbọ́ tèmi! Ẹ rán àwọn ìgbékùn tí ẹ̀yin ti mú gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹlẹwọ̀n padà nítorí ìbínú kíkan Olúwa ńbẹ lórí yín.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:11 ni o tọ