Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 27:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jótanì sì ṣẹ́ ogun lórí ọba àwọn ará Ámónì ó sì borí wọn. Ní ọdún náà àwọn ará Ámórì wọ́n sì san fún ọgọ́rùn-ún tálẹ́ńtì fàdákà àti ẹgbàaàrún òsùwọ̀n àlìkámà àti ẹgbàárún balì. Àwọn ará Ámónì gbé e wá ní iye kan náà àti pẹ̀lú ní ọdún kejì àti ní ọdún kẹta.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 27

Wo 2 Kíróníkà 27:5 ni o tọ