Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jótámù sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì di ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́rìndínlógun. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Jérúsà ọmọbìnrin Sádókì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 27

Wo 2 Kíróníkà 27:1 ni o tọ