Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 26:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì lọ sí ogun lórí Fílístínì ó sì wó odi Gátì lulẹ̀, Jábìnè àti Ásídódù. Ó sì kó ìlú rẹ̀ tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ Ásídódù àti níbì kan láàrin àwọn ará Fílístínì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:6 ni o tọ