Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ùsáyà sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún méjìléláadọ́ta. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Jekolíà; ó sì wá láti Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:3 ni o tọ