Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 26:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ùsía, ẹni tí ó ní àwo tùràrí ní ọwọ́ rẹ̀ tó ṣe tán láti sun tùràrí, ó sì bínú. Nígbà tí ó sì ń bínú sí àwọn àlùfáà níwájú wọn, níwájú pẹpẹ tùràrí ní ilé Olúwa, ẹ̀tẹ̀ sì yọ jáde ní iwájú orí rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:19 ni o tọ