Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 26:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún ilé ìṣọ́ ihà kọ́, ó sì gbẹ́ kàǹga púpọ̀, nítorí ó ni ẹran ọ̀sìn púpọ̀ ní ilẹ̀ aṣálẹ̀ àti ní pẹ̀tẹ́lẹ̀. Ó sì ní àwọn ènìyàn tí ń ṣiṣẹ́ ní pápá àti ọgbààjàrà ní orí òkè ní ilẹ̀ ọlọ́ràá, nítorí ó fẹ́ràn àgbẹ̀ ṣíṣe.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:10 ni o tọ