Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà gbogbo ènìyàn Júdà mú Ùsáyà, ẹni tí ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún (16) wọ́n sì fi jẹ ọba ní ipò baba rẹ̀ Ámásíà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 26

Wo 2 Kíróníkà 26:1 ni o tọ