Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀ kò pa àwọn ọmọ wọn, ṣùgbọ́n ó ṣe ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí a kọ nínú òfin nínú ìwé Mósè, níbi tí Olúwa ti paláṣẹ pé: “A kò gbọdọ̀ pa àwọn baba fún àwọn ọmọ wọn tàbí àwọn ọmọ fún baba wọn; Olúkúlùkù ni kí ó kú fún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:4 ni o tọ