Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ wí fún ara à rẹ wí pé, ìwọ ti ṣẹ́gun Édómù àti nísinsin yìí ìwọ ní ìrera àti ìgbéraga. Ṣùgbọ́n dúró ní ilé! Kí ni ó dé tí o fi n wá wàhálà tí o sì fi ń fa ìṣubú rẹ àti ti Júdà pẹ̀lu?”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:19 ni o tọ