Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámásíà jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n nígbà tí ó di ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Jéhóadánì, ó wá láti Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:1 ni o tọ