Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 22:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ìgbà ìbẹ̀wò Áhásáyà sí Jórámí, Ọlọ́run mú ìṣubú Áhásáyà wá. Nígbà tí Áhásáyà dé, ó jáde lọ pẹ̀lú Jórámì láti lọ bá Jéhù ọmọ Nímísì, ẹni tí Olúwa ti fi àmì òróró yàn láti pa ìdílé Áhábù run.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:7 ni o tọ