Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tẹ̀lé ìgbìmọ̀ wọn nígbà tí ó lọ pẹ̀lú Jórámì ọmọ Áhábù ọba Ísírẹ́lì láti gbógun ti Háṣáélì ọba Árámì ní Rámótì Gílíádì. Àwọn ará Árámì ṣá Jórámì lọ́gbẹ́;

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:5 ni o tọ