Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 20:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élísérì ọmọ Dáfídì ti Máréṣà sọtẹ́lẹ̀ sí Jóhóṣáfátì, wí pe, “Nítorí tí ìwọ ti da ara rẹ̀ pọ̀ mọ́ Áhásáyà, Olúwa yóò pa ohun ti iwọ ti ṣe run.” Àwọn ọkọ̀ náà sì fọ́, wọn kò sì le lọ sí ibi ìtajà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:37 ni o tọ