Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹ̀rin, wọn kó ara jọpọ̀ ní àfonífojì ìbùkún, níbi tí wọ́n ti ń fi ìbùkún fún Olúwa. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní àfonífojì ìbùkún títí di òní.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:26 ni o tọ