Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 20:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Àwọn èníyàn Júdà jáde sí ìhà ilé ìsọ́ ní ihà, wọn ń wo àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn, òkú nìkan ni wọ́n rí tí ó ṣubú sí ilẹ̀, kò sì sí ẹnìkan tí ó rí àyè sá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:24 ni o tọ