Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fi igi òpépé ránṣẹ́ sí mi, pínì àti lígúmì àwọn igi láti Lébánónì, nítorí tí mo mọ̀ pé àwọn ọkùnrin rẹ ní ìmọ̀ nínú gígé igi rírẹ́. Àwọn ọkùnrin mi yóò ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọkùnrin rẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:8 ni o tọ