Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ta ni ó le è kọ́ ilé fún Olúwa, níwọ̀n ìgbà tí àwọn ọ̀run, àní ọ̀run tí ó ga jùlọ, kò ti le è gbà á? Ta ni èmi nígbà náà láti kọ́ ilé fún Olúwa, àyàfi ibi kan fún sísun ẹbọ níwájú rẹ̀?

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:6 ni o tọ