Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 17:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ní ìṣúra ní ìlu Júdà. Ó sì tún ní àwọn alágbára jagunjagun akọni ọkùnrin ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 17

Wo 2 Kíróníkà 17:13 ni o tọ