Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jáde lọ bá Ásà, ó sì wí fún un pé, “Tẹ́tí si mi Ásà, àti gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì. Olúwa wà pẹ̀lú rẹ, nígbà tí ìwọ bá wà pẹ̀lú rẹ̀. Ti ìwọ bá wá a, ìwọ yóò rí i ní ẹ̀bá rẹ ṣùgbọ́n tí ìwọ bá kọ̀ ọ́ silẹ̀, òun yóò kọ̀ ọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 15

Wo 2 Kíróníkà 15:2 ni o tọ