Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ásà rọ ìyá ńlá rẹ̀ Mákà lóyè láti ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìyá ọba nítorí tí ó ti ṣe òpó Áṣérà tí ń lé ni sá. Ásà gé òpó náà lulẹ̀, wòó, ó sì jóo ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kídírónì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 15

Wo 2 Kíróníkà 15:16 ni o tọ