Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíjà sì sinmi pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀, a sì sin ín sínú ìlú ńlá ti Dáfídì. Ásà ọmọ rẹ̀ rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba. Ní àwọn ọjọ́ rẹ̀, orílẹ̀ èdè wà ní àlàáfíà fún ọdun mẹ́wàá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:1 ni o tọ