Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsìn yìí, ìwọ ṣètò láti kọ́ ìjọba Olúwa, tí ó wà lọ́wọ́ àwọn àtẹ̀lé Dáfídì. Ìwọ jẹ́ ọmọ ogun tí ó gbilẹ̀, ìwọ sì ní pẹ̀lu rẹ ẹgbọrọ màlúù wúrà ti Jéróbóámù dà láti se Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 13

Wo 2 Kíróníkà 13:8 ni o tọ