Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àràárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́, wọ́n gbé ọrẹ sísun àti tùràrí olóòórùn dídùn síwájú Olúwa. Wọ́n gbé àkàrà jáde sórí tábìlì àsè mímọ́, wọ́n sì tan iná sí àwọn fìtílà lórí ìdúró ọ̀pá fìtílà wúrà ní gbogbo ìrọ̀lẹ́. A ń pa àṣẹ Olúwa Ọlọ́run wa mọ́. Ṣùgbọ́n ìwọ ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 13

Wo 2 Kíróníkà 13:11 ni o tọ