Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Ṣíṣákì ọba Éjíbítì dojúkọ Jérúsálẹ́mù, ó gbé àwọn ìṣúra ilé Olúwa, àti àwọn ìsúra ààfin ọba. Ó gbé gbogbo rẹ̀, pẹ̀lú àwọn àpáta wúrà tí Sólómónì dá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:9 ni o tọ