Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èyí ní ohun tí Olúwa wí. Ẹ má ṣe gòkè lọ lati lọ jà pẹ̀lú arákùnrin yín, ẹ lọ sílé, gbogbo yín, nítorí ti ìṣe mi nìyí.’ ” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n tẹ̀lé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wọ́n sì padà sẹ́yìn láti yan lọ dojúkọ Jéróbóámù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 11

Wo 2 Kíróníkà 11:4 ni o tọ