Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Kí ni ìmọ̀ràn yín? Báwo ni kí a ṣe dá àwọn ènìyàn wọ̀nyí tí wọ́n wí fún mi pé, ‘Mú kí àjàgà tí baba rẹ gbé lé wa kí ó fúyẹ́ díẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 10

Wo 2 Kíróníkà 10:9 ni o tọ