Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì dáhùn, “Tí ìwọ yóò bá ṣe rere sí àwọn ènìyàn wọ̀nyí kí o sì ṣe ire fún wọn kí o sì fún wọn ní ìdáhùn rere, wọn yóò sì máa jẹ́ ìránṣẹ́ rẹ nígbà gbogbo.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 10

Wo 2 Kíróníkà 10:7 ni o tọ