Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì gòkè lọ sí ibi pẹpẹ idẹ níwájú Olúwa ní ibi àgọ́ ìpàdé, ó sì rú ẹgbẹ̀run ọrẹ sísun lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:6 ni o tọ