Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúẹ́lì dáhùn pé, “Èmi ni wòlíì náà. Ẹ máa gòkè lọ ṣáájú mi, ní ibi gíga, ẹ ó sì bá mi jẹun lónìí. Ní òwúrọ̀ ni èmi yóò tó jẹ́ kí ẹ lọ, gbogbo ohun tí ó wà ní ọkàn rẹ ní èmi yóò sọ fún ọ.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 9

Wo 1 Sámúẹ́lì 9:19 ni o tọ