Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gòkè lọ sí ìlú náà, bí wọ́n ti ń wọlé, níbẹ̀ ni Sámúẹ́lì, ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ wọn bí ó ti ń lọ ibi gíga náà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 9

Wo 1 Sámúẹ́lì 9:14 ni o tọ