Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sọ fún Sámúẹ́lì pé, “Má ṣe dákẹ́ kíké pe Olúwa Ọlọ́run wa fún wa, ké pè é kí ó lè gbà wá kúrò lọ́wọ́ àwọn Fílístínì.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 7

Wo 1 Sámúẹ́lì 7:8 ni o tọ