Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni, Sámúẹ́lì wí pé, “Ẹ kó gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ sí Mísípà, èmi yóò bẹ̀bẹ̀ fún un yín lọ́dọ̀ Olúwa.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 7

Wo 1 Sámúẹ́lì 7:5 ni o tọ