Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin tí ó mú ìròyìn náà wá dáhùn pé, “Ísírẹ́lì sá níwájú àwọn Fílístínì, àwọn ọmọ ogun náà sì kú lọ́pọ̀lọpọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fínéhásì, wọ́n kú, wọ́n sì ti gba àpótí ẹ̀rí Olúwa lọ”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 4

Wo 1 Sámúẹ́lì 4:17 ni o tọ