Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì gbé ogun lọ síhà Gúúsù tí ara Kérítì, àti sí ìhà ti Júdà, àti sí ìhà Gúúsù ti Kélẹ́bù; àwa sì kun Síkílágì ní iná.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 30

Wo 1 Sámúẹ́lì 30:14 ni o tọ