Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sáré lọ sí ọ̀dọ̀ Élì ó sì wí pé, “Èmi nìyí nítorí pé ìwọ pè mí.”Ṣùgbọ́n Élì wí fún-un pé, “Èmi kò pè ọ́; padà lọ dùbúlẹ̀.” Nítorí náà ó lọ ó sì lọ dùbúlẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 3

Wo 1 Sámúẹ́lì 3:5 ni o tọ