Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èmi sọ fún un pé, Èmi yóò ṣe ìdájọ́ fún ilé rẹ̀ títí láé nítorí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ wọn tí òun mọ̀ nípa rẹ̀ nítorí àwọn ọmọ rẹ̀ sọ ọ̀rọ̀ òdì, òun kò sì dá wọn lẹ́kun.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 3

Wo 1 Sámúẹ́lì 3:13 ni o tọ