Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Sámúẹ́lì pé, “Wò ó, èmi ṣetán láti ṣe ohun kan ní Ísírẹ́lì tí yóò jẹ́ kí etí gbogbo ènìyàn tí ó gbọ́ ọ já gooro.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 3

Wo 1 Sámúẹ́lì 3:11 ni o tọ