Dáfídì sì wí fún Ákíṣì, pé, “Nítòótọ́ ìwọ ó sì mọ ohun tí ìránṣẹ rẹ lè ṣe.”Ákíṣì sì wí fún Dáfídì pé, “Nítorí náà ni èmi ó ṣe fi ìwọ ṣe olùṣọ́ orí mi ni gbogbo ọjọ́.”