Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 28:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún un pé, “Má ṣe bẹ̀rù; kín ni ìwọ rí?”Obìnrin náà sì wí fún Ṣọ́ọ̀lù pé, “Èmi rí ẹ̀mí kan tí ó ti ilẹ̀ wá.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 28

Wo 1 Sámúẹ́lì 28:13 ni o tọ