Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 26:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì kọ sí àwọn ènìyàn náà àti sí Ábínérì ọmọ Nérì wí pé, “Ìwọ kò dáhùn, Ábínérì?”Nígbà náà ni Ábínérì sì dáhùn wí pé, “Ìwọ ta ni ń pe ọba?”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 26

Wo 1 Sámúẹ́lì 26:14 ni o tọ