Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì wí fún àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ pé, “Èèwọ̀ ni fún mi láti ọdọ Olúwa wá bí èmi bá ṣe nǹkan yìí sí ẹni tí a ti fi àmì òróró Olúwa yàn, láti nawọ́ mi sí i, nítorí pé ẹni-àmì-òróró Olúwa ni.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 24

Wo 1 Sámúẹ́lì 24:6 ni o tọ