Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 24:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Wò ó, èmi mọ̀ nísinsin yìí pé, nítòótọ́ ìwọ ó jẹ ọba, àti pé ìjọba Ísírẹ́lì yóò sì fi ìdí múlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ.

21. Sì búra fún mi nísinsin yìí ní orúkọ Olúwa, pé, ìwọ kì yóò gé irú ọmọ mi kúrò lẹ́yin mi, àti pé, ìwọ kì yóò pa orukọ mi run kúrò ní ìdílé baba mi.”

22. Dáfídì sì búra fún Ṣọ́ọ̀lù. Ṣọ́ọ̀lù sì lọ sí ilé rẹ̀; ṣùgbọ́n Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì gòkè lọ sí ihò náà.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 24