Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 24:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, ojú rẹ́ ríi lónìí, bí Olúwa ti fi ìwọ lé mi lọ́wọ́ lónìí nínú ihò; àwọn kan ní kí èmi ó pa ọ; ṣùgbọ́n èmi dá ọ sí; ‘Èmi sì wí pé, èmi kì yóò nawọ́ mi sí olúwa mi, nítorí pé ẹni-àmì-òróró Olúwa ni òun jẹ́.’

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 24

Wo 1 Sámúẹ́lì 24:10 ni o tọ