Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì sọ fún Ṣọ́ọ̀lù pé Dáfídì wá sí Kéílà. Ṣọ́ọ̀lù sì wí pé, “Ọlọ́run ti fi í lé mi lọ́wọ́; nítorí tí ó ti sé ara rẹ̀ mọ́ ní ti wíwá tí ó wá sí ìlú tí ó ní ìlẹ̀kùn àti kẹrẹ.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:7 ni o tọ