Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì béèré lọ́dọ̀ Olúwa pé, “Ṣé kí èmi ó lọ kọlu àwọn ará Fílístínì wọ̀nyí bí?” Olúwa sì wí fún Dáfídì pé, “Lọ kí o sì kọlu àwọn ará Fílístínì kí o sì gba Kéílà sílẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:2 ni o tọ