Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì ọmọ Ṣọ́ọ̀lù sì dìde, ó sì tọ Dáfídì lọ nínú igbó náà, ó sì gbà á ní ìyànjú nípa ti Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:16 ni o tọ