Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì wí pé, “Àwọn àgbà ilú Kéílà yóò fi èmi àti àwọn ọmọkùnrin mi lé Ṣọ́ọ̀lù lọ́wọ́ bí?” Olúwa sì wí pé, “Wọn ó fi ọ́ lé wọn lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:12 ni o tọ