Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 22:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí gbogbo yín di ìmọ̀lù sí mi, tí kò sì sí ẹnìkan tí ó sọ létí mi pé, ọmọ mi ti bá ọmọ Jésè mulẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kó sì sí ẹnìkan nínú yín tí ó ṣàánú mi, tí ó sì sọ ọ́ létí mi pé, ọmọ mi mú kí ìránṣẹ́ mi dìde sí mi láti ba dè mí, bí ó ti rí lónìí.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 22

Wo 1 Sámúẹ́lì 22:8 ni o tọ